Orílẹ̀-èdè Dominican Republic ló wà nípò kìíní nínú àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè mẹ́wàá tó láyọ̀ jù lọ lágbàáyé, àwọn orílẹ̀-èdè bíi Sri Lanka, Tanzania, Panama, Malaysia, Nigeria, Venezuela, El Salvador, Costa Rica, àti Uruguay ló sì tẹ̀ lé e.
#WORLD #Yoruba #ID
Read more at asianews.network